Ẹ WO ỌSIBITU IJỌBA NIPINLẸ KOGI BO ṢE RI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, November 13, 2019

Ẹ WO ỌSIBITU IJỌBA NIPINLẸ KOGI BO ṢE RI

Eyi ni apa kan lara Ọsibitu ijọba to wa ni Idah nipinlẹ Kogi, ọpọ awọn to n de bẹ ni wọn n bu sẹkun pẹluu bi ijọba ko ṣe wa nnkan ṣe sii.

A gbọ pe o n fa akoba si ilera awọn alaisan, paapaa awọn oṣiṣẹ ọsibitu naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI