ARABINRIN ANYANWU AKEREDOLU FAWỌN AGUNBANIRỌ TO ṢIṢẸ LABẸ RẸ LẸBUN NLA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, November 22, 2019

ARABINRIN ANYANWU AKEREDOLU FAWỌN AGUNBANIRỌ TO ṢIṢẸ LABẸ RẸ LẸBUN NLA

Gbogbo awọn agunbanirọ ipin kẹta (Batch C) to ṣiṣẹ labẹ iyawo Gomina ipinlẹ Ondo, Arabinrin Arabinrin Betty Anyanwu Akeredolu ni wọn ṣi n dupẹ lọwọ obinrin naa fun ẹbun ẹrọ Kọmputa aalagbeeka (Laptop) ti wọn ri gba.

Ọjọru tiii ṣe Wẹside to kọja yi la gbọ pe Arabinrin Betty Akeredolu ṣayẹyẹ idagbere fun gbogbo wọn nileeṣẹ Gomina ipinlẹ naa to wa lagbegbe Alagbaka niluu Akurẹ.









No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI