ILE ẸJỌ TRIBUNA DA ẸSUN TI WỌN FI KAN GANDUJE NU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, October 2, 2019

ILE ẸJỌ TRIBUNA DA ẸSUN TI WỌN FI KAN GANDUJE NU

Lonii ni ile ẹjọ Tribuna da ẹsun ti ẹgbẹ oṣelu PDP ati Oludije sipo gomina wọn fi kan Gomina Abdullahi Umar Ganduje danu wi pe ko lẹsẹ nilẹ, ati pe ẹsun ti ko ni awijare lasan ni.

Onidajọ Mohammed Halima Shamaki to dari igbẹjọ naa lo fidi ẹ mulẹ nibi idajọ ti ko din ni wakati mẹrin naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI