Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara niluu Ilọrin ti kede sita pe awọn n wa ọdọmọbinrin ẹni ọdun mọkandinlogun kan, Sa'adat Ọlajumọkẹ Bakare ti wọn lawọn obi ẹ ko ri lati ọjọ Aje Mọnde ọsẹ to kọja yi, iyẹn ọjọ keji oṣu ti a wa yi.
Akẹkọọ fasiti ipinlẹ Kwara tiluu ilọrin, iyẹn University of Ilorin la gbọ pe Ọlajumọkẹ wa ni ẹka ikẹkọọ iṣẹ ile ati ounjẹ igbalode ti Oloyinbo n pe ni Home Economics and Food Science
Department.
Fun ẹnikẹni to ba kofiri Ọlajumọkẹ, awọn nọmba yi ni ki ẹ pe 08062623867 or 08056678859
No comments:
Post a Comment