Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, awọn
ọmọ Naijiria ti ko din ni mẹtalelogun lo ti wa lorilẹ-ede yi bayii latari ẹsun
gbigbe kokeeni ti wọn fi kan wọn lorilẹ-ede Saudi Arabia.
Adeniyi Adebayọ Zikri, Tunde Ibrahim, Jimọh Idhola Lawal, Lolo Babatunde, Sulaiman Tunde, Idris Adewunmi Adepọju, Abdul-Raimi Awẹla Ajibọla, Yusuf Makeen Ajiboye, Adam Idris Abubakar, Saka Zakaria, Biọla Lawal, Isa Abubakar Adam, Ibrahim Chiroma, Hafis Amosu ati Aliu Muhammad.
Awọn to ku ni: Funmilayọ Ọmọyẹmi Bishi, Mistura Yẹkini, Amina Ajọkẹ Alọbi, Kuburat Ibrahim, Alaja Olufunkẹ Alalaoe Abdulqadir, Fawsat Balogun Alabi, Aisha Muhammad Amira ati Adebayọ Zakariya.
Bẹ o ba gbagbe, lai pẹ yi ni
wọn dajọ fun ọmọ Naijiria kan, Kudirat Afolabi lori ẹsun gbigbe kokeeni, to si
tun jẹ pe ko pẹ lọwọ tun tẹ Saheed Ṣobade pẹluu kokeeni ti ko din ni iwọn ẹgbẹrun kan (1,183) giraamu niluu Jeddah.
No comments:
Post a Comment