Ojule kẹẹdogun, adugbo Alado, Shibiri lọwọ ti tẹ wọn nigba ti wọn sọ pe Yusuf Abu, ọmọ ogun ọdun lo fẹẹ gbawọn eeyan wọle sinu ẹgbẹ okunkun ti wọn pe ni One Milion Boys naa.
Awọn tọwọ tẹ naa ni Sunday Gabriel, ọmọ ogun ọdun; Rilwan Dauda, ọmọdun mejidinlogun; Mohammed Sikiru, ọmọdun mẹtalelogun; Ọladimeji
Abayọmi, ọmọdun mejidinlogun; Rasheed Alabi, ọmọ ogun ọdun; Habeeb Idowu, ọmọdun mejidinlogun; Bisọla Ọlaiya, ọmọdun mejidinlogunati Hawawu Hazzan toun jẹ ọmọdun mọkandinlogun.
No comments:
Post a Comment