ỌDAJU ABIYAMỌ RE O: BABA LU ỌMỌ RẸ, ỌMỌDUN MẸTA NILUKULU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, August 19, 2019

ỌDAJU ABIYAMỌ RE O: BABA LU ỌMỌ RẸ, ỌMỌDUN MẸTA NILUKULU

Bo tilẹ jẹ pe a ko ti mọ nnkan to ṣẹlẹ laarin baba ati ọmọ rẹ, ọmọdun mẹta, to mu ki baba naa daa dubulẹ, to si ko patiẹ bo o bii maalu to gbọjọ iku.

Ilu Ogbomọṣọ nipinlẹ Ọyọ niṣẹlẹ naa ti waye lọjọ Satide to kọja yi.

 
A gbọ pe baba naa ati iyawo to ṣẹṣẹ fẹ ni wọn jọ dawọ bo ọmọdun mẹta naa, to si jẹ pe awọn ẹlẹyinju aanu ni wọn gba ọmọ naa silẹ.

Fọto ọmọ naa lẹ n wo yii.

1 comment:

PÍN-IN KÁÀKIRI