ILÉYÁ: ÌWÀ ÀLÀÁFÍÀ LO ṢE PÀTÀKÌ LÁSÌKÒ ÀTI LẸ́YÌN ILÉYÁ - ỌNỌREBU TUNJI-ÒJÓ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, August 12, 2019

ILÉYÁ: ÌWÀ ÀLÀÁFÍÀ LO ṢE PÀTÀKÌ LÁSÌKÒ ÀTI LẸ́YÌN ILÉYÁ - ỌNỌREBU TUNJI-ÒJÓ


Ọnọrebu Olubunmi Tunji-Ojo to ń ṣojú ẹkùn Akoko North East/North West nílé igbimọ aṣojú-ṣofin nílùú Abuja tí gba gbogbo àwọn lẹ́yìn Anọbi lamọnran pé kí wọn ríi dájú pé ìfẹ́ ati àlàáfíà tí wọn lo nile Àdúrà, ìyẹn Yidi lónìí náà ni kí wọn máa fi bá ara wọn lo pọ títí ayé, nítorí pé nnkan tó ṣe pàtàkì julọ nìyẹn.

Ó sọrọ náà laarọ ana nínú ọ̀rọ̀ ikinni to fi ranṣẹ s'AWIKONKO, eyi to fi ki awọn Musulumi lorilẹ-ede Naijiria, paapaa ipinlẹ Ondo nigba to n gba gbogbo awọn ọmọ lẹyin Anọbi lamọnran fun ti ayẹyẹ ọdun Ileya.

Nibẹ lo ti ni ki wọn ri i daju pe wọn n mu ifẹ Ọlọun wọn lo nipa fifi awọn awọn ẹkọ ati ilana naa si ojuṣe.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI