Ṣe lọrọ di boolọ o yago lọjọ Aiku, Sande ana nigba ti wọn lawọn Hausa ati Yoruba kọju ija sira wọn, ti wọn bẹrẹ sii ṣe ara wọn baṣubaṣu, ko da, ti ọpọ dukia ṣofo danu, tawọn eeyan si farapa yannayanna.
Agbegbe ọja nla kan to wa ni Oke-Odo nipinlẹ Eko, loju ọna Ekoo si Abẹokuta nija nla naa ti waye, to si jẹ pe fun bi i wakati mẹrin lagbegbe naa fi pa lọọlọ.
Diẹ re e lara awọn fọto iṣẹlẹ naa.
No comments:
Post a Comment