ERELU FAYẸMI RE E PẸLUU AARẸ ẸGBẸ AWỌN ONKỌWE LORILẸ-EDE NAIJIRIA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, August 17, 2019

ERELU FAYẸMI RE E PẸLUU AARẸ ẸGBẸ AWỌN ONKỌWE LORILẸ-EDE NAIJIRIA

Lọjọbọ, Tọside ọsẹ to kọja yi ni ẹgbẹ awọn onkọwe loriulẹ-ede Najiria, iyẹn Association of Nigerian Authors (ANA), ẹka tipinlẹ Ekiti fi Gomina ipinlẹ naa, Dọkitọ Kayọde Fayẹmi ṣe baba isalẹ wọn.

Nibẹ naa ni wọn ti da iyawo Gomina Fayẹmi, Erelu Bisi Fayẹmi naa lọla rẹpẹtẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI