WỌN TI JU AWỌN ỌMỌ YAHOO MẸRIN SẸWỌN L'ABUJA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, July 24, 2019

WỌN TI JU AWỌN ỌMỌ YAHOO MẸRIN SẸWỌN L'ABUJA

Ile ẹjọ giga kan to fikalẹ sagbegbe Nyanya niluu Abuja ti ju awọn ọdọmọkunrin mẹrin kan sẹwọn laipẹ yi, latari ẹsun ti wọn fi kan wọn, eyi to nii ṣe pẹluu jibiti ori ayelujara, iyẹn Yahoo-Yahoo.

 
Awọn mẹrin naa ni Tosan Ogbe, Onajite Tosan Ejivwo, Abdulmumin Saidu ati Karo Ijire ni wọn kawọ pọyin niwaju Onidajọ Muawiyah Baba Idris, ti wọn si n bẹbẹ fun idariji, lẹyin ti wọn gba pe awọn jẹbi awọn ẹsun ti wọn fi kan wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI