Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, Aarẹ ana lorilẹ-ede Naijiria, Goodluck Ebele Jonathan ti gba oye tuntun nilẹ Ibo, iyẹn niluu Onitsha.
Bẹ o ba gbagbe, lọsẹ to kọja ni Goodluck Johnathan ṣabẹwọ lọọ si Aafin Obi tiluu Onitsha, nibẹ ni wọn ti fi oye tuntun da a lọla gẹgẹ bi ọkan lara awọn to n gbe ilẹ Ibo larugẹ kaakiri agbaye.
Diẹ lara awọn fọto ibi ti wọn ti da a lọla niwọn yii.
No comments:
Post a Comment