Laipẹ yi ni gbajugba oṣere tiata oloyinbo nni, Rita Dominic le ni ọdun kan loke eepẹ, to si ṣayẹyẹ nla lati fi mu inu ara rẹ dun.
Ọpọ awọn eeyan lagbo amuludun ni wọn ko le fi para lati ma yọju sibi ayẹyẹ naa. Lara wọn ni Richard Mofẹ-Damijo,
DBanj, Kate Henshaw, Tokẹ Makinwa, Ini Ẹdọ, Peter Okoye, Uche Jombo atawọn min in.
Diẹ re lara awọn fọto ayẹyẹ ọjọ ibi naa:
No comments:
Post a Comment