ỌRẸ MẸRIN TO N JALE WỌ GAU L'ONDO, ILUKULU NI WỌN FI TUN AYE WỌN ṢE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, July 20, 2019

ỌRẸ MẸRIN TO N JALE WỌ GAU L'ONDO, ILUKULU NI WỌN FI TUN AYE WỌN ṢE

Bi awọn ọrẹ mẹrin ti a ko tii mọ orukọ wọn dasiko ti a ṣakojọpọ iroyin yi tan ba fi le tun aye wa, bi wọn ba ya sidi ole jija, a jẹ pe oogun idile lo n ba wọn finra.

 
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn loo ti pẹ ti awọn ọrẹ mẹrin naa ti n jale niluu Awoye, to wa nijọba ibilẹ Ilajẹ, ipinlẹ Ondo, to si jẹ pe aarọ oni Abamẹta laṣiri wọn tu nigba ti wọn lọọ ja ileeṣẹ kan lole.

 
Ẹrọ nla kan ti wọn pe ni 40Hp Yamaha Engine ni wọn ji gbe, to si jẹ pe asiko ti wọn n gbe e lọ lọwọ tẹ wọn.
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI