Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, inu idunnu ati ayọ ni gbajugba oṣere tiata nni, Ọmọtọla Jolade Ẹkẹinde wa bayii pẹluu bi ọmọ ẹ Michael ṣe kẹkọọ gboye ni fasiti Eastern Mediterranean
to wa ni Cyprus.
Ori ikanni ayelujara Instagram ni gbajugbaja nna gbe fọto naa si, nibi to ti n jẹ kawọn eeyan mọ pe ọmọ oun ti kẹkọọ gboye, ki wọn ki oun ku oriire.
No comments:
Post a Comment