Bo tilẹ jẹ pe iyalẹnu lọrọ gbajumọ oṣere tiata nni, Liz Anjọrin ṣi n jẹ fun ọpọ awọn eeyan, paapaa awọn oṣere ẹgbẹ rẹ lori ile olowo nla tuntun to ṣẹṣẹ pari sagbegbe ijọba ibilẹ Eti-Ọsa niluu Ekoo, bẹẹ awọn eeyan lo n ki ku oriire.
Bẹ o ba gbagbe, lọdun to kọja ni Liz Anjọrin ra mọto olowo nla kan, to si ni kawọn eeyan ṣi maa reti nnkan nla min in , tori pe iyẹn naa yoo tun ya wọn lẹnu, to si jẹ pe loootọ, nigba to gbe ẹri naa sori ayelujara rẹ, agba iyanu lo jẹ.
Congratulations
ReplyDelete