Ilu mọn ọn ka oṣere tiata orilẹede Ghana nni, Xandy Kamel ti sọ pe latigba toun ti wa kekere loun ti n gbadun ibalọpọ, paapaa nigba toun wa ni ipele kẹrin nile ẹkọ alakọbẹrẹ, iyẹn Primary 4 loun ti n ni ibalopọ, ti ko si jọ oun loju mọ rara.
Kamel lo sọrọ yi nigba to n tako iroyin kan to n lọ kaakiri ori ayelujara pe ibalopọ lo fi n gba okiki nidi iṣẹ tiata, ati pe bi ko ba gbe idi silẹ fawọn alakoso ere, wọn kii lo lati kopa.
O ni iroyin ti wọn n gbe kaakiri naa ki i ṣe toun nitori pe kaakiri ilu ti wọn ti bi oun loun gbajumọ sii, ko da, nigba toun wa nile ẹkọ girama
O wa a jẹ ko di mimọ pe kii ṣe ibalopọ loun fi n gba okiki, nitori pe kii ṣe nnkan to jọ oun loju mọ lati fi di olokiki nidi iṣẹ naa.
No comments:
Post a Comment