Ọrọ kan to n lọ kaakiri ikaani ayelujara lasiko yi ni ti ọdọmọbinrin agunbanirọ kan ti ko ni apa ọwọ, to si n ya awọn eeyan lẹnu nipa bo ṣe gba ile-ẹkọ kọja , to fi de ipele agunbanirọ.
Bo tilẹ jẹ pe kii ṣe bi wọn bi agunbanirọ naa niyẹn, ṣugbọn lojiji lo padanu ọwọ ẹ mejeeji sinu ijamba kan lọdun diẹ sẹyin, to si pinu pe oun yoo kẹkọọ gboye lai nii wo ti ipenija to wa lara oun.
Titi dasiko ta a fi ko iroyin yi jọ la ko tii mọ orukọ agunbanirọ naa.
No comments:
Post a Comment