AKẸKỌỌ FASITI AHMADU BELLO GBE OOGUN JẸ, LẸSẸKẸSẸ LO KU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, July 7, 2019

AKẸKỌỌ FASITI AHMADU BELLO GBE OOGUN JẸ, LẸSẸKẸSẸ LO KU

 
Titi di asiko tia  ṣakojọpọ iroyin yi tan la ko tii le sọ nipa idi ti akẹkọọ ile ẹkọ fasiti Ahmadu Bello nipinlẹ Zaria, Nafeezat Abdul fi dee de gbe oogun jẹ lati gba ẹmi ara rẹ.

 
Ipele keji ni Nafeezat wa nile ẹkọ naa, ti a si gbọ pe ọkan lara awọn ọrẹ ẹ to fọrọ lọ ti gba a lamọnran pe ko ma ṣe gbẹmi ara rẹ.

  Image may contain: one or more people and shoes

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI