Titi di bi ẹ ṣe n ka iroyin yi lo ṣi n ṣe pupọ ninu awọn ọmọ Naijiria, paapaa awọn ti wọn ko tii da ile aye lasiko idibo naa lẹnu, pẹlu bi Aarẹ tẹlẹri, Oloogbe Sanni Abacha ṣe da ibo naa nu.
Friday, June 14, 2019
WỌNYII NI ẸKUNRẸRẸ ESI IBO JUNE 12, 1993 ATI IDI TI BABANGIDA ṢE DAA NU
Tags
# IDIBO
# Oselu
PIN-IN KAAKIRI
NIPA IROYIN AWIKONKO
Oselu
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
PÍN-IN KÁÀKIRI
Author Details
Ile-iṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL lo n gbe IROYIN AWIKONKO jade pẹlu ontẹ Ijọba orilẹ-ede Naijiria labẹ ajọ iforukọsilẹ nni, iyẹn CORPORATE AFFAIRS COMMISSION. A fẹ ki ẹyin ti ẹ n ka Iroyin Awikonko mọ daju pe a ko ni i gba ẹnikẹni laaye lati ṣe ẹda iroyin wa, tabi gbe e jade ninu iwe iroyin min in lai gba aṣẹ lọwọ awọn alaṣẹ wa, ẹsẹ ofin la o fi gbe onitọhun. Bẹẹ, a ko ni fẹ ki ẹnikẹni ṣi iroyin wa ka, nitori pe iwadii kikun la n ṣe ka to le gbe iroyin jade, nitori naa, bi ẹ ba ka ifọrọwerọ pẹlu eeyan, ohun ti ẹni naa ba sọ, ki i ṣe awa la sọ ọ, ẹni naa lo sọ bẹẹ. Fun alaye lẹkunrẹrẹ, tabi ipolowo ọja yin, ẹ le kan si wa lori: +2347012342712.
No comments:
Post a Comment