WỌN JA ỌLỌMỌGE MẸTA SIHOHO L'ABUJA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 27, 2019

WỌN JA ỌLỌMỌGE MẸTA SIHOHO L'ABUJA

 
Lọjọ Tuside to kọja yi ni wọn lawọn janduku ja awọn ọlọmọge arẹwa mẹta kan sihoho ọmọluabi latari ẹsun ti wọn fi kan wọn pe ajinigbe ni wọn.

Yatọ sawọn ọlọmọge arẹwa mẹta wọnyii, bẹẹ ni wọn tun ja baale ile kan naa ti wọn loun lo n gbe kaakiri ibi ti wọn ti ji awọn eeyan gbe, ta a si tun gbọ pe wọn dana sun mọto wọn kọja afẹnusọ.

A ti ẹ gbọ pe ọkunrin kan lo tu aṣiri wọn pe oun wa nibẹ nigba ti wọn ji obinrin kan gbe ni Dutse.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI