UGANDA: ILE ẸJỌ GIGA LAWỌN ỌKUNRIN LE MAA FẸ ARA WỌN, BẸẸ LAWỌN OBINRIN NAA LANFAANI LATI GBE ARA WỌN SILE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 13, 2019

UGANDA: ILE ẸJỌ GIGA LAWỌN ỌKUNRIN LE MAA FẸ ARA WỌN, BẸẸ LAWỌN OBINRIN NAA LANFAANI LATI GBE ARA WỌN SILE

Pupọ ninu awọn to gbọ iroyin naa pe ile ẹjọ giga ti orilẹ-ede Ecuadọr ti paṣẹ pe aaye ṣi silẹ fawọn ọkunrin lati maa gbe ara wọn sile, bẹẹ lawọn obinrin naa le ma gbe ara wọn sile gẹgẹ bi ọkọ atiyawo lo ṣi n ṣe ni kayeefi titi dasiko yii.

Oni eyi yoo tun lọ ninu ofin ilẹ South Amẹrika ti Katoliiki.

Bawọn kan ṣe n dunnu, bẹẹ lawọn kan n bu sẹkun pe opin aye ti de loootọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI