Séti eré idaraya niká so tàbí tí
aso-tòhun-tisè-alaranbara tí wó n wò níbè?
Àyíká naa je ojú ní gbèsè, aso ara sìse pàtàkì bíi
esin naa se jé.
Eré esin naa dàbi pé kòní ìgbá àbí àsìkò ni.
Eré esin náa kò túnwá dàbí ilé nla kan ràgbàdù bí
àafin tó wà l'àyika náá tí wo n pè ní Grand Chateau.
Mo gbósùbà
fún ògá ògo nígbà tí mo gánní ilé òhun. Ó tóbí, ó tún wá gùn.
Grand Chateau òhún ti wà láti 1600. Sùgbón wón ti
wóo, won tún ti tún kó leyin ìgbà naa.
Eré elésin yen ni ìlà mèta tí o wo inú ara won. Ilè
onígi loo yika. Sítandi nla kan sì wà níbè láti 1879.
Àayè náá tí n gba Prix du Jockey Club làlejò lati
1836 pèlú Prix de Diane lati 1843.
No comments:
Post a Comment