Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun
"O TO O GẸ Ẹ, AKETI, Ẹ WA MA A LỌ" ti wọn lawọn ẹgbẹ kan ti wọn pe ara wọn ni Hope of The Masses n kọ bayii nipinlẹ Ondo fun Gomina wọn, Ọgbẹni Rotimi Akeredolu, pe asiko ẹ ti to.
Gẹgẹ b'AWIKONKO ṣe gbọ, wọn ni ọrọ Gomina Akeredolu ti su awọn araalu, ati pe ọkunrin kan ni fẹẹ ṣagbatẹru ẹ ninu idibo ti yoo tun waye lọdun 2020.
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ lai pẹ.
No comments:
Post a Comment