Ṣẹnkẹn bayii ninu gbogbo awọn aṣoju-ṣofin ipinlẹ Ogun n dun pẹlu bi wọn ṣe yan Ọnọrebu Ọlakunle Oluọmọ gẹgẹ bi abẹnugọn ile igbimọ aṣofin.
Yatọ sí pe wọn kò dibo kankan rara, a gbọ pe Ọnọrebu Oludare Kadiri toun wa lati Ijẹbu North II lo di igbakeji rẹ.
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ iroyin n bọ lai pẹ.
No comments:
Post a Comment