OJU TI AWỌN ẸLẸGAN: LAWAN BURA FUN OKOROCHA GẸGẸ BI SẸNETỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 13, 2019

OJU TI AWỌN ẸLẸGAN: LAWAN BURA FUN OKOROCHA GẸGẸ BI SẸNETỌ

Aarẹ ile igbimọ aṣofin agba oriulẹ-ede yi, Ahmad Lawan laarọ oni Tọside ti bura fun Gomina ana nipinlẹ Imo, Rochas Okorocha gẹgẹ bii sẹnetọ to jawe olubori ninu idibo apapọ orilẹ-ede yi to kọja.

Ọjọ Tuside ijẹta lo yẹ ki wọn bura fun Okorocha, ṣugbọn ti ajọ INEC ko fun un ni iwe ẹri ẹ, ṣugbọn ni bayii, Aarẹ Lawan ti bura fun sẹnetọ fun Okorocha lati ṣoju ẹkun Imo West nile igbimọ aṣofin agba orilẹ-ede Naijiria.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI