Orin 'A ti t'oje bọ olooṣa lọwọ, o ku baba nla ẹni ti yoo bọ' lawọn aṣofin atawọn aṣoju-ṣofin orilẹ-ede yi n kọ bayii, latari ipo Aarẹ ile igbimọ aṣofin agba ati abẹnugọn ile igbimọ aṣoju-ṣofin to ṣi silẹ. Ibeere tawọn ọmọ Naijiria n beere lọwọ ara wọn bayii ni pe 'Tani ipo mejeeji yi yoo ja mọ lọwọ?'
![](https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEiwwaBodb0RK1S6phbYsId93WQngqJcibziWp6svgig6OZsBT7RtFZuJYBAEot1RK5jAVMEuT6lpq27fmGCeqh7Xp0vj5ohsbwP4erhUpjo7WCLn8vZK5dt09BXNxrrWQYDpdG57XgYEjQ/s1600/POLITY-skeapership-and-senate-president.jpg)
No comments:
Post a Comment