O KU DẸDẸ KI ỌLỌMỌGE KẸKỌỌ GBOYE LO GBE MAJELE JẸ NITORI AFẸSỌNA Ẹ TO KỌ Ọ SILẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, June 19, 2019

O KU DẸDẸ KI ỌLỌMỌGE KẸKỌỌ GBOYE LO GBE MAJELE JẸ NITORI AFẸSỌNA Ẹ TO KỌ Ọ SILẸ

Gbenga Ọladipupọ

Titi dasiko ti a kọ iroyin yi tan, lọrọ iku akẹkọọbinrin kan ti wọn pe orukọ ẹ ni Christabel Boro ti ẹka ikẹkọọ eto ilera (Medical Laboratory Science) nipele kẹta ti ile ẹkọ fasiti Benin, UNIBEN ṣi n jẹ kayeefi fawọn eeyan lori bo ṣe dee de gbẹmi ara rẹ lojiji.

 
Ọjọ Tuside ana la gbọ pe Christabẹl gbe oogun jẹ ni nnkan bi aago meje kọja iṣẹju mẹẹdogun irọlẹ.

 
Wọn ni ṣe lo kọ lẹta silẹ, to si jẹ ko ye awọn eeyan pe ọkọ afẹsọna oun lo kọ oun silẹ lojiji pe oun ko ṣe mọ, toun ko si le gba a lo jẹ koun pa ara ouhn.
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI