Ẹgbẹ awọn akẹkọọ (National Association of
Nigeria Students) nipinlẹ Ogun, ti sọ pe igbesẹ ti Gomina Dapọ Abiọdun gbe lati yanju awọn wahala to n ṣẹlẹ nile ẹkọ Tai Ṣolarin to wa ni Omu-Ijẹbu nipinlẹ naa ko ṣe e fọwọ rọ ti ṣeyin tori pe igbesẹ alaafia ni.
Nigba to n gbe oṣuba kare fun Gomina Abiọdun, Kọmureedi Bamgboṣe Tọmiwa sọ pe igbesẹ ti Gomina gbe lati pana wahala ti MAPOLY jẹ eyi ti ko sẹni to le tete gbagbe titi lai, tawọn yoo si maa yin in titi aye.
No comments:
Post a Comment