FỌTO: ERO RẸPẸTẸ NIBI ISINKU DAGUNRO L'OṢOGBO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 13, 2019

FỌTO: ERO RẸPẸTẸ NIBI ISINKU DAGUNRO L'OṢOGBO

Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun

 
Ko sẹni to le rọ ẹnikan lẹkun nibi ti wọn ti sinku gbajugbaja oṣere tiata to jade laye laarọ onii, Oloogbe Ọlabankẹwin, ẹni tawọn eeyan mọ si Dagunro.
Ko da a, ẹsẹ ko gbero lagbegbe Isalẹ Ọṣun nibi ti wọn sin Oloogbe naa sii.


 
 
 
  

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI