Lọjọ Satide Abamẹta ana ni iyawo Gomina ipinlẹ Ekiti, Erelu Bisi Fayẹmi ṣabẹwo akanṣe si Mama agbalagba kan ti wọn ni ogbologbo ọmọ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) nipinlẹ Ekiti.
Mama naa, Iwa Adefarakan la gbọ pe ilu Ọrin-Ekiti lo fi ṣebugbe, ti Erelu Fayẹmi si tun da a lọla rẹpẹtẹ pẹlu abẹwo to ṣe lati fi ẹmi imọ-oore han.
No comments:
Post a Comment