AWỌN TỌỌGI LU ỌṢIỌMỌLẸ LALUBAMI L'ẸDO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, June 19, 2019

AWỌN TỌỌGI LU ỌṢIỌMỌLẸ LALUBAMI L'ẸDO

Ọjọ manigbagbe lọjọ Tuside ana yi jẹ fun Gomina ana nipinlẹ Ẹdo, Adams Ọṣiọmọlẹ nigba ti wọn lawọn tọọgi kan lọọ dena de aburo rẹ, Seidu Ọṣiọmọlẹ ti won si luu lalubami.

Yatọ si Ọṣiọmọlẹ, wọn tun lu awọn aṣofin mẹrin ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan nipinlẹ Ẹdo lasiko ti wọn n ṣe ipade kan lọwọ. Ijọba ipinlẹ naa la gbọ pe o ran awọn tọọgi naa lati lọọ ṣe wọn baṣubaṣu.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI