AWỌN ṢỌJA TI RỌWỌ TO OGBOLOGBO AJINIGBE TO N FI AṢỌ ṢỌJA ṢIṢẸ BURUKU L'ONDO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, June 11, 2019

AWỌN ṢỌJA TI RỌWỌ TO OGBOLOGBO AJINIGBE TO N FI AṢỌ ṢỌJA ṢIṢẸ BURUKU L'ONDO

 
Kani baale ile ẹni ọdun mejidinlogojin kan, Victor John mọ pe aṣiri oun yoo pada tu ni, boya ki ba ti tete so ewe agbejẹ mọwọ, ko too di pe akara ẹ yoo pada tu sepo ni.

Ọrẹ nijọba ibilẹ Odigbo, Akurẹ lọwọ palaba John ti segi nigba tọwọ awọn ologun to n gbogun ti iwa ajinigb ti 32 Artillery Brigade ti Owena barrack tẹ ẹ laarọ oni.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI