Titi aye lawọn adignunjale kan tọwọ awọn ọlọpaa kogberegbe, iyẹn SARS tẹ lọsan yi ko le gbagbe iya to jẹ wọn.
Ohun ta a gbọ ni pe awọn adigunjale naa lo lọọ ja ọkunrin kan lole, ṣugbọn tọwọ pada tẹ wọn, to si jẹ pe ita gbangba lawọn SARS naa ti da seria fun wọn nigba ti wọn sọ pe wọn n ba wọn lo agidi.
Ipinlẹ Ṣokoto niṣẹlẹ naa ti waye gẹgẹ bi a ṣe gbọ. Wọn ni bawọn ọdaran yi ṣe rii pe asiko naa lawọn SARS n kọja lọ, lo mu ki wọn gbiyanju lati na papa bora, ṣugbọn tọwọ pada tẹ wọn, ti wọn si da ijamba mọto silẹ.
Diẹ tun re e lara awọn fọto wọn.
No comments:
Post a Comment