Pupọ ninu awọn to ri awọn fọto tọkọ-tiyawo oju ọna yi ni wọn n woye pe bawo ni wọn ṣe fẹẹ maa gbe latari bi wọn ṣe sanra-rọbọtọ.
Bawọn eeyan ṣe n sọ oriṣiriṣi la rii pe awọn tọkọ-tiyawo ti wọn palẹmọ igbeyawo wọn ko ti ẹ rii ro rara, di po bẹẹ ṣe nifẹ wọn tun ga sii.
No comments:
Post a Comment