Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun
Lati le mu ki idagbasoke eto ọrọ aje ipinlẹ Ekiti le tubọ dagba sii, awọn alaṣẹ, apaṣẹ ati oludari Banki Union ti lọọ ṣabẹwo akanṣẹ si Gomina ipinlẹ Ekiti, Dọkita Kayọde Fayẹmi.
Lati le mu ki idagbasoke eto ọrọ aje ipinlẹ Ekiti le tubọ dagba sii, awọn alaṣẹ, apaṣẹ ati oludari Banki Union ti lọọ ṣabẹwo akanṣẹ si Gomina ipinlẹ Ekiti, Dọkita Kayọde Fayẹmi.
Ọjọ Mọnde to kọja yi lawọn eeyan naa ti oludari agba fun Banki naa, Ọgbẹni Emeka Emuna lewaju wọn lọọ ki Gomina Fayẹmi ni ọfiisi Gomina to wa ni Ado-Ekiti, ti wọn si sọ bi eto ọrọ aje yoo ṣe tẹsiwaju sii.
Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ féyinti pẹlu Gomina Fayẹmi |
Ninu iroyin min in to tun fara pẹ ẹ ni bi ẹgbẹ awọn akọwe agba lẹka iṣẹ ijọba ti wọn fẹyinti nipinlẹ naa tun ṣe ipade pẹlu Gomina Fayẹmi.
Lara wọn to wa nibẹ ni Alaaji Ọladoro Yakubu Sanni, Oloye Deji Faṣuan, Oloye Abiọdun Ajayi ati Pasitọ Richard
Adejuyigbe.
No comments:
Post a Comment