ỌBASANJỌ WỌ SUUTU, LAWỌN EEYAN BA N SỌ ORIṢIRIṢI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, May 2, 2019

ỌBASANJỌ WỌ SUUTU, LAWỌN EEYAN BA N SỌ ORIṢIRIṢI

Ko sẹni to ri Aarẹ tẹlẹri lorileede Naijiria, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ninu aṣọ oyinbo, iyẹn suutu lonii, ti ko ṣe ni kayeefi.

Idi ni pe, latigba ti Oloye Ọbasanjọ ti wọn tun n pe ni Ẹbọra Owu ti di Aarẹ orileede yi ni ko ti fi bẹẹ wọ awọn aṣọ to jẹ tawọn oloyinbo.

Aṣọ ibilẹ ni Ọbasanjọ fẹran lati maa wọ, idi ni yii tawọn to ri fọto Aarẹ ana naa fi sọ oriṣiriṣi nipa ẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI