KAYEEFI NLA: WỌN YINBỌN PA OLOYE ẸGBẸ OṢELU APC - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, May 9, 2019

KAYEEFI NLA: WỌN YINBỌN PA OLOYE ẸGBẸ OṢELU APC

Bọ tilẹ jẹ pe iwadii ti bẹrẹ lori awọn agbebọn kan ti wọn yinbọn pa ọkan lara awọn Oloye ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Rivers, Ọnọrebu Omunakwe lalẹ ana, Wẹside, sibẹ iyalẹnu lo ṣi n jẹ fawọn araalu.

Oloye ẹgbẹ oṣelu APC Obio-Akpor ni Oloogbe Omunakwe, bẹẹ lo tun jẹ ọkan lara awọn adije sipo ọmo ile igbimọ aṣofin ri.

Apopona 24 Agip Estate, ijọba ibile Mgboshimimi niluu port Harcourt ni wọn ti da ọkunrin naa duro, ki wọn too da ẹmi ẹ legbodo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI