Titi lailai lawọn omo Yoruba kaakiri agbaye yoo fi maa ranti Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja keji fun ti igbelaruge aṣa, iṣọkan ati ifẹ to n polongo laarin awọn ọmọ Yoruba.
Ana tii se Satide Abamẹta ni Ooni Ile Ifẹ, Ọba Adeyẹye tun kuro ni Aafin ẹ, to si lọọ ki Gomina tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan nipinlẹ Ogun, Ọmọba Dapọ Abiọdun nile ẹ to wa ni Ipẹru fun ti aṣeyọri ẹ, ati ipalẹmọ igbakoso.
No comments:
Post a Comment