Gbọ ẹgbẹ akọroyin lorileede Naijiria, paapaa nipinlẹ Ogun ni wọn ṣi n fi atẹjiṣẹ ọjọ ibi ranṣẹ si ọkan lara wọn, Arabinrin Oluwaṣeun Idowu Boye. Oni ni ayẹyẹ ọjọ ibi ẹ.
Arabinrin Boye jẹ gbajumọ akọroyin nipinlẹ Ogun, oun si ni ọga agba akọroyin fun ẹka ileeṣẹ ijọba to n ri sọrọ oye jijẹ ati ijọba ibilẹ.
Diẹ re lara awọn fọto ayẹyẹ ọjọ ibi naa to n lọ lọwọ dasiko ta a kọ iroyin yi tan.
Gbogbo awọn alaṣẹ ati apaṣẹ ileeṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL ni wọn n fi asiko yi ki obinrin naa pe iba ọdun, ọdun kan ni o
No comments:
Post a Comment