FAYẸMI, ỌṢỌBA, KACHUKWU PADE NIBI AAMI ẸYẸ ZIK L'EKOO (FỌTO) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, May 27, 2019

FAYẸMI, ỌṢỌBA, KACHUKWU PADE NIBI AAMI ẸYẸ ZIK L'EKOO (FỌTO)

Gomina tẹlẹri nipinlẹ Ekiti, Ọtunba Niyi Adebayọ; Gomina tẹlẹri nipinlẹ Ogun, Oloye Oluṣẹgun Ọṣọba; Gomina ipinlẹ Ekiti, Dokitọ Kayọde Fayẹmi ati iyawo ẹ, Erelu Bisi Fayẹmi to gba aami ẹyẹ ZIK.
Iyawo gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Erelu Angela Adebayọ; Gomina tẹlẹri nipinlẹ Ekiti, Ọtunba Niyi Adebayọ; Gomina ipinlẹ Ekiti, Dokitọ Kayọde Fayẹmi ati iyawo ẹ, Erelu Bisi Fayẹmi to gba aami ẹyẹ ZIK; Igbakeji Gomina tẹlẹ nipinlẹ Ekiti, Ọjọgbọn Modupẹ Adelabu.
Inu gbọngan ayẹyẹ Civic Center to wa l'Ekoo ni eto naa ti waya lọjọ Sande ana an. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI