Ẹ WOJU AWỌN ỌDARAN T'ỌWỌ TẸ NIPINLẸ OGUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, May 24, 2019

Ẹ WOJU AWỌN ỌDARAN T'ỌWỌ TẸ NIPINLẸ OGUN

L'ọjọ Wẹside to kọja yi ni olu-ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun labẹ ọga agba Bashir Makama foju awọn ọdaran ni ti ko din ni Ogun han fawọn oniroyin ninu ọgba wọn to wa ni Eleweran, Abẹokuta.
Ọpọ awọn to ri awọn eeyan yi lo n ṣe ni kayeefi latari awọn ọṣẹ ati kankan ibilẹ, ti wọn ni lawọn ọdaran yi maa n wẹ lati gba kadara awọn to ba ko si akolo wọn.
Nibẹ naa ni wọn tun ti foju baale ile kan to n jẹ Tunde han fawọn oniroyin, ẹni ti wọn lo n ṣe ayederu egboogi mimu, ti wọn pe ni Ṣẹnuẹbo lagbegbe Mowe/Ibafo.
Bawọn ọmọ Yahoo ṣe wa ninu wọn, bẹẹ lawọn ọmọ ẹlẹgbẹ okunkun naa wa lara wọn.

Babatunde to n ṣe ayederu egbooji ibilẹ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI