Ìgbà kẹta rèé léra wọn ti ìyà ń
ba ìyà fún ìkọ ẹgbẹ́ àgbabọọlu Arsenal, èyí sì mú wọn to sẹ̀yìn Chelsea ti yóò
koju Manchester United ní old Trafford
Nínú ìfẹsẹwọnsẹ tó tún wáyé
lónìí láàrin Leicester City àti Arsenal ní wọn ti gbẹwuro àmi àyó mẹ́ta si òdo
fún Arsenal.
Ìgbáju ìgbámú ni Leiscester
city ǹko fún Arsenal, eyí ti ó si ń ṣe ọkàn láàrẹ pe sé ìrètí Arsenal ó ti ré
bọ sinu omi báyìí?
Kó dáju mọ báyìí bọ́ya Arsenal
yóò kógojá fún Champions League.
Ibéèrè ti ó ń wáye fún Unai
Emery ni pé níbo ni Arsenal ń lọ niniúdíje Champions League yìí
Ẹ̀ẹ̀mèji ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni Jamie
Vardy Gbá bọ́ọ̀l sáwọn láti gbọn búrẹdi Arsenal jábọ kúrò nínú àwọn ti yóò kopa
nínú ìdíje Champions League.
Bíi wákati kan gbáko ni Arsenal
fui n dàmú lóri pápá lái kó èrè oko déle, bí wọn ṣe ràn Ainsley Maitland niṣẹ́
láti ló gbá èwé jọkó jẹ́jẹ́ wá.
Bótilẹ jẹ je Arsenal si ni
ànfàni láti pari si ipò keeje bi ìdílje ṣe ku méji sẹyi, èyi lé mu wọn kóju
òsùwọn
láti kopa ninu Europa League,
wọn ni àmi àyo márun ti wọn fi n toò sẹ́yin Wolves
No comments:
Post a Comment