WỌN NI AARẸ BUHARI FẸRAN ẸYA IBO JU GBOGBO AWỌN AARẸ TO TI JẸ LỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, April 29, 2019

WỌN NI AARẸ BUHARI FẸRAN ẸYA IBO JU GBOGBO AWỌN AARẸ TO TI JẸ LỌ

Ẹgbẹ awọn ọdọ ti Ọhanaeze Ndigbo lọjọ Sande ana ti sọ ọ nita gbangba pe Aarẹ Muhammadu Buhari nikan lo nifẹ awọn ara South-East laarin awọn Aarẹ orileede Naijiria to ti n jẹ latẹyin wa lọ.

Aarẹ ẹgbẹ naa, Okechukwu Isiguzoro lo sọrọ yi lasiko to n bawọn oniroyin sọrọ niluu Abakaliki to jẹ olu-ilu ipinlẹ Ẹbonyi.

O s'ọrọ yi lati fi tako ọrọ ti wọn ni Aarẹ patapata fun ẹgbẹ naa sọ laipẹ yi pe ijọna ẹlẹyamẹya ni Aarẹ Buhari n ṣe lorileede yi lọwọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI