Macron ni
ile ijọsin naa wa lara itan ayanmọ ilẹ Faranse ni eyi ti ẹnikẹni ko le gbagbe.
O n beere
fun ifọwọsowọpọ gbobo eniyan Faranse nile ati loke okun ki wọn le jọ yanju ọrọ
naa.
Àwọn òṣìṣẹ́
pàjáwìrì ti pa'ná tó jó ìjọ àgùdà tí wọ́n f'igba ọdún kọ́.
Macron fi
soju òpó ayelujara rẹ pe, iṣẹ ajumọṣe ni atunṣe ile ijọsin naa yoo jẹ pe, iṣẹ ti
de naa ni yẹn lori orirun wọn.
Lọjọ kẹẹdogun,
oṣu kẹrin, ọdun 2019 ni iná sọ ni Notre Dame
Awọn oṣiṣe
pajawiri ti pa ina to jo ile ijọsin atayedaye Notre-Dame Cathedral to wa ni ilu
Paris, orilẹede France, eyi ti ina bọ si ni ọjọ Aje.
Ijọba orilẹede
naa ni ko ti si ẹni to le sọ pato oun to fa ina na to ran de awọn apa ibomiiran
ninu ọgba rẹ.
Ina naa ba ọpọ
awọn to fẹran itan atayedaye ninu jẹ nitori ọjọ ori ile ijọsin naa. Itan sọ fun
wa wipe, fun igba ọdun ni wọn fi kọ ile ijọsin Notre-Dame Cathedral ati wipe ọdun
aadọtalelẹgbẹrin sẹyin ni wọn ti kọ.
Aarẹ orilẹede
France, Emmanuel Macron ti ṣe ileri lati tun ile ijọsin naa ṣe lẹyin ina naa.
Se ni o ta
kan de ibi ti ina naa ti n jo lẹyin to fagile eto ọrọ to gbero lati ba awọn ọmọ
orilẹ-ede naa sọ lonii.
Ọgbẹni Macro
ni "bi gbogbo ọmọ orilẹ-ede mi, inu mi bajẹ lalẹ yii lati ri ibi to n jona
yii".
Lọdun to kọja
ni ijọ naa ṣe ikowojọ oni pajawiri ni orilẹ-ede France lati wa owo ti wọn yoo
fi tun ijọ to ti pe ọdun ẹgbẹjọ o le aadọta naa kọ eyi to ti bẹrẹ si ni da wo.
Media
captionÀàrẹ Buhari ti gba Ààrẹ Macron ti orílẹ̀èdè France lálejò nilu Abuja
Awọn oṣiṣẹ
pana-pana ti n ṣe iṣ lọ ni pẹrwu lati gbiyanju dida ọwọ ina naa duro.
- BBC YORUBA
No comments:
Post a Comment