ANFAANI NLA RE E FAWỌN ỌDỌ LATI DI OLOWO NLA PẸLU FOONU WỌN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, April 19, 2019

ANFAANI NLA RE E FAWỌN ỌDỌ LATI DI OLOWO NLA PẸLU FOONU WỌN


Pupọ ninu awọn ọdọ lorileede Naijiria ni wọn n lo foonu to ni anfaani intanẹẹti, ṣugbọn ti wọn ko mọ pe ṣe lawọn kan n san owo danu fawọn ileeṣẹ ikansiraẹni lasan ni, ati pe oriṣiriṣi ọna lo wa ti wọn le fi di olowo yanturu pẹlu foonu wọn.

Eto kan ti wọn pe ni MEGA EMPLOYMENT SKILLZ ti ileeṣẹ VAM NIGERIA ṣagbatẹru ẹ lati ran awọn ọdọ lọwọ lo n lọ lọwọ bayii, ti yoo si kasẹ nilẹ laago mejila ku iṣẹju kan alẹ oni Fraide rere (Good Friday.

Lati bi oṣu meloo kan sẹyin ni anfaani naa ti jade sita, ti pupọ ninu awọn ọdọ ti wọn ko fẹẹ ṣe ẹru ẹgbẹ wọn si ti gba fọọmu lati jẹ ninu anfaani nla naa, ko da a, tawọn kan ti n dunnu pe oriire nla ti de ba wọn.

Gẹgẹ bi AWIKONKO to jẹ ọkan lara awọn to n ṣagbatẹru eto yi ṣe gbọ, wọn ni ori ikanni ibanisọrọ lori foonu, iyẹn WhatsApp ni idanilẹkọọ nipa anfaani naa yoo ti wayefun ọjọ mẹwaa gbako.

Oni tii ṣe ọjọ kọkandinlogun oṣu kẹrin ni idanilẹkọọ naa yoo bẹrẹ laago mẹrin irọlẹ, ti yoo si pari lọjọ kejidinlọgbọn oṣu yi bakan naa, laago mejila ku iṣẹju kan gbako.

Idanilẹkọọ naa ni awọn alaṣẹ ati apaṣẹ ileeṣẹ VAM NIGERIA atawọn to ṣagbatẹru ẹ ni wọn fẹẹ fi din iṣẹ ati oṣi laarin awọn ọdọ ku.

Lara awọn nnkan ti wọn fẹẹ ṣe idanilẹkọọ le lori ni:

Bi a ṣe n ri ojulowo ara ẹni, iyẹn Self Discovery
Gbigbe iṣẹ ara ẹni larugẹ, iyẹn Enterprise Development.

Awọn ọna min in ni bi ẹ ṣe le lo foonu yin lọna igbalode bii:
 
Constructive CV Writing/Design
Tracking Recently Lost Phones
Social Media Marketing To boost your Business
Creating a Blog Website
Basic Guides to Web Design
Converting Websites, Blogs, Forum to Android Applications
Designing Business Card
ID Cards and Logos Designing
Designing Certificates
Converting Handwritten/Hard copy Text to Soft Copy

ati bi ẹ ṣe le di ri owo lori awọn nnkan wọnyii.

Ẹgbẹrun meji pere lẹ o fi jẹ anfaani yi. Bi ẹ ba si fẹẹ san owo ti yin, wonyi ni apo owo ti ẹ maa san owo si:

Bank: UBA
Account: 2056899616
Name: Olorungbotemi Tunde Bright
tabi
Bank: Access Bank
Account: 0778758675
Name: Olorungbotemi Tunde Bright.

Fun alaye lẹkunrẹrẹ, ẹ le pe  08072633727 tabi ẹ ka si ikanni WhatsApp yi.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI