Awọn mọlẹbi oloogbe nni,
Temitọpẹ Ọlatoye tọpọ awọn eeyan mọ si Ṣugar ti sọ pe ọjọ keji, oṣu karun ọdun
yi ni wọn yoo sinku ẹ.
Gẹgẹ bi aburo oloogbe naa,
Dọtun Ọlatoye ṣe ṣalaye fawọn oniroyin laipẹ yi, o sọ pe dandan ni kawọn sinku
eeyan wọn, bo tilẹ jẹ pe ibanujẹ ṣi ni iku ẹ jẹ fawọn.
Bẹ o ba gbagbe, ninu idibo to kọja
lọ ni wọn ti yinbon fun aṣoju-ṣofin agbegbe Lagelu si Akinyẹle.
No comments:
Post a Comment