WỌN NI WỌLE ỌKẸ ATI DPO ỌLỌPAA N FI TỌỌGI DA IGBORO RU L’ỌṢUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, February 2, 2019

WỌN NI WỌLE ỌKẸ ATI DPO ỌLỌPAA N FI TỌỌGI DA IGBORO RU L’ỌṢUN


Irọ nla ni, ko ri bẹẹ - Wọle Ọkẹ


Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun

Aburo mi ni Ṣiji Ọlamiju, ko le si wahala laarin wa lailai - Wọle Ọkẹ

Aofin to n ṣoju awn eeyan lagbegbe Oriade/bkun nile igbimọ aofin apap orileede yii, narebu Oluwọle Ọkẹ ti sọ pe ko si ootọ ninu ahesọ kan to n lọ kaakiri pe awọn alatilẹyin oun da wahala silẹ lagbegbe yẹn laipẹ yii.

Ọkẹ, to n sr lori sun kan ti oludije labẹ gb oelu APC lagbegbe naa, Dkita Siji lamiju fi kan an laip yii pe o ko awn nnkan ija oloro wọ agbegbe ọhun pelu ifwsowp DPO lpaa nib.

Ọnarebu yii ni gg bii Amofin ati Aṣofin, oun m ewu to wa ninu kiko ibn kaakiri lai gba aṣẹ ld awn lpaa, oun ko si ni aṣẹ (license) naa lw rara lati ṣe iru nnkan bẹẹ.

Image may contain: 6 people, beard
Nibi ikọlu to waye laipẹ yi
O ni aburo oun ni lamiju, oun ko si si nipinl Ọṣun lasiko ti wahala ti wn n s ọhun ṣẹlẹ, ati pe awn m gb APC ti wn j alatilyin lamiju ni wn da wahala naa sil lyin ti Dọkita naa fun wn ni owo ti ko tẹ wn lrun nigba to abwo sd wọn.

Ọkẹ fi kun r r pe oun ko m DPO ti wn n s yn ri rara nitori ko si idi kankan toun fi le maa e wlewde plu . O ni ai tii mọ oelu e daadaa lo fa wahala fun lamiju.

Image may contain: 1 person, car 
O ni odu ni oun ninu oelu agbegbe Oriade/bkun, kii e aimọ fun oloko, awn nnkan meremere toun si ti e fawn araalu lo fa a ti awn alatilyin oun ninu gb oselu APC gan an fi po ju ti inu gb PDP gan an l.

Gbogbo nnkan yii ti lamiju ri lo sọ pe o fa a to fi n wa gbogbo na lati fa oun sinu wahala, eleyi ti oun ko si le faaye rẹ sil lailai nitori aburo lo j fun oun ni gbogbo na.

O waa r awn alatilyin lati ma e faaye gba nikni lati bi wn ninu, aaju, lasiko ati lyin idibo j krindinlogun ou keji dun yii.

Bẹẹ lo r awn m gb APC lati dkun iwa ipa nitori idibo.

#Agbala Iroyin

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI