Bọsun Ọlaniyi, Abeokuta
Ko si orin meji tawọn eeyan tun
n sọrọ nipa lasiko yi bi ko ṣe orin tuntun ti ọkan lara awọn ti Ọlọrun fi iṣẹ
orin ran, Guccimaneko ṣẹṣẹ gbe jade sita, eyi to pe ni ‘No Case’.
Kii ṣe bi orin naa ṣe jade
nikan lo jẹ kawọn eeyan maa sọrọ nipa ẹ, bi ko ṣe awọn ogbontarigi onkọrin
takasufe to fi mọ gbajumọ olorin Fuji nni, Alaaji Wasiu Alabi Pasuma tun ṣe
kopa ninu ẹ.
Lara awọn to tun wa ninu orin
naa ni Davido ati DJ Jimmy Jatt.
No comments:
Post a Comment