Nigba to n
ka esi ibo aarẹ ti wọn di lọjọ Satide nijọba ibilẹ Surulere, asoju ajọ Inec to
se akoso ibo nibẹ salaye pe, rogbodiyan to waye ati bi wọn se n ji apoti ibo
gbe, lo jẹ ki iye ibo ti wọn wọgile fi pọ to bẹẹ.
Lẹyin o rẹyin,
ni wọn kede ibo aarẹ lati mọ iye ibo ti Atiku Abubakar tẹgbẹ oselu PDP ati
Muhammadu Buhari ti ẹgbẹ APC ni.
PDP: 31,603
APC: 30,621
Ibo ti wọn
gba wọle: 65784
Ibo ti wọn
danu: 4904
Apapọ iye
ibo ti wọn di: 70688
- BBC
No comments:
Post a Comment